Jẹ́nẹ́sísì 18:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọkùnrin náà yí padà, wọ́n sì ń lọ sí ìhà Ṣódómù. Ṣùgbọ́n Ábúráhámù dúró níbẹ̀ níwájú Olúwa.

Jẹ́nẹ́sísì 18

Jẹ́nẹ́sísì 18:13-26