Jẹ́nẹ́sísì 18:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sì wí pé, igbe Ṣódómù àti Gòmórà pọ̀ púpọ̀ àti pé ẹ̀ṣẹ̀ wọn burú jọjọ.

Jẹ́nẹ́sísì 18

Jẹ́nẹ́sísì 18:18-24