Jẹ́nẹ́sísì 18:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ ohunkóhun wà tí ó sòro jù fún Olúwa? Èmi ó padà tọ̀ ọ́ wá ní ìwòyí àmọ́dún, Ṣárà yóò si bí ọmọkùnrin.”

Jẹ́nẹ́sísì 18

Jẹ́nẹ́sísì 18:4-18