Jẹ́nẹ́sísì 17:26-27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

26. Ábúráhámù pẹ̀lú rẹ̀ kọ ilà ní ọjọ́ náà gan-an.

27. Àti gbogbo ọkùnrin tí ó wà ní ilé Ábúráhámù, ìbá à ṣe èyí tí a bí ní ilé rẹ̀ tàbí èyí tí a fi owó rà lọ́wọ́ àlejò ni a kọ ní ílà pẹ̀lú rẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 17