Jẹ́nẹ́sísì 17:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run wí fún Ábúráhámù pé, “Ní ti Ṣáráì, aya rẹ̀, ìwọ kì yóò pè é ní Ṣáráì bí kò ṣe Ṣárà.

Jẹ́nẹ́sísì 17

Jẹ́nẹ́sísì 17:6-20