Jẹ́nẹ́sísì 17:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbá à ṣe ẹni tí a bí nínú ilé rẹ, tàbí ẹni tí fi owó rà, gbọdọ̀ kọ wọ́n ní ilà; májẹ̀mú mí lára yín yóò jẹ́ májẹ̀mú ayérayé.

Jẹ́nẹ́sísì 17

Jẹ́nẹ́sísì 17:6-15