Jẹ́nẹ́sísì 16:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábúrámù dáhùn pé, “Ìwọ ló ni ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ, ṣe ohunkóhun tí ó bá tọ́ ní ojú rẹ sí i.” Nígbà náà ni Ṣáráì fi ìyà jẹ ẹ́, ó sì sá lọ.

Jẹ́nẹ́sísì 16

Jẹ́nẹ́sísì 16:5-13