Jẹ́nẹ́sísì 15:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì tún wí fún un pé, “Èmi ni Olúwa tí ó mú ọ jáde láti Úrì ti Kálídéà láti fún ọ ní ilẹ̀ yìí láti jogún.”

Jẹ́nẹ́sísì 15

Jẹ́nẹ́sísì 15:3-10