Jẹ́nẹ́sísì 14:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo àwọn ọba wọ̀nyí ni ó kó ogun wọn jọ pọ̀ sí àfonífojì Ṣídímù (òkun iyọ̀).

Jẹ́nẹ́sísì 14

Jẹ́nẹ́sísì 14:1-4