Jẹ́nẹ́sísì 14:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi kì yóò gba ohunkóhun yàtọ̀ sí ohun tí àwọn ọkùnrin mi ti jẹ́, ṣùgbọ́n fi ìpín fún àwọn ọkùnrin tí ó bá mi lọ, Ánérì, Ésíkólì àti Mámúrè. Jẹ́ kí wọn kí ó gba ìpín wọn.”

Jẹ́nẹ́sísì 14

Jẹ́nẹ́sísì 14:18-24