Jẹ́nẹ́sísì 14:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba Ṣódómù sì wí fún Ábúrámù pé, “Kó àwọn ènìyàn mi fún mi, ṣùgbọ́n mú àwọn ẹrù fún ara rẹ.”

Jẹ́nẹ́sísì 14

Jẹ́nẹ́sísì 14:17-24