Jẹ́nẹ́sísì 13:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo ilẹ̀ ha kọ́ nìyí níwájú rẹ? Jẹ́ kí a pínyà. Bí ìwọ bá lọ sí apá ọ̀tún, èmi yóò lọ sí apá òsì, bí ó sì ṣe òsì ni ìwo lọ, èmi yóò lọ sí apá ọ̀tún.”

Jẹ́nẹ́sísì 13

Jẹ́nẹ́sísì 13:5-18