Jẹ́nẹ́sísì 13:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo ilẹ̀ tí ìwọ ń wò o nì ní èmi ó fi fún ọ àti irú ọmọ rẹ láéláé.

Jẹ́nẹ́sísì 13

Jẹ́nẹ́sísì 13:6-18