Jẹ́nẹ́sísì 12:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábúrámù sì rìn la ilẹ̀ náà já títí dé ibi igi ńlá kan tí à ń pè ni Móórè ní Ṣékémù. Àwọn ará Kénánì sì wà ní ilẹ̀ náà.

Jẹ́nẹ́sísì 12

Jẹ́nẹ́sísì 12:1-7