Jẹ́nẹ́sísì 12:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn tí ó súre fún ọ ni Èmi yóò súre fún,ẹnikẹ́ni tí ó bá sì fi ọ́ ré ni Èmi yóò fi ré;Nípaṣẹ̀ rẹ ni a ó sì bùkúngbogbo ènìyàn ayé”

Jẹ́nẹ́sísì 12

Jẹ́nẹ́sísì 12:1-6