Jẹ́nẹ́sísì 12:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì kẹ́ Ábúrámù dáradára nítorí Ṣáráì, Ábúrámù sì ní àgùntàn àti màlúù, akọ àti abo, kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, ìránṣẹ́kùnrin àti ìránṣẹ́bìnrin, pẹ̀lú u ràkunmí.

Jẹ́nẹ́sísì 12

Jẹ́nẹ́sísì 12:9-20