Jẹ́nẹ́sísì 12:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó ti ku díẹ̀ kí ó wọ Éjíbítì, ó wí fún Ṣáráì, aya rẹ̀ pé, “Mo mọ̀ pé arẹwà obìnrin ni ìwọ,

Jẹ́nẹ́sísì 12

Jẹ́nẹ́sísì 12:3-20