Jẹ́nẹ́sísì 11:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìdí èyí ni a fi pè é ní Bábílónì nítorí ní ibẹ̀ ni Ọlọ́run ti da èdè gbogbo ayé rú, tí ó sì tú àwọn ènìyàn ká sí gbogbo orí ilẹ̀ ayé.

Jẹ́nẹ́sísì 11

Jẹ́nẹ́sísì 11:7-13