Jẹ́nẹ́sísì 11:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀ wá, ẹ jẹ́ kí a sọ̀kalẹ̀ lọ, kí a da èdè wọn rú kí èdè wọn má baà yé ara wọn mọ́.”

Jẹ́nẹ́sísì 11

Jẹ́nẹ́sísì 11:1-13