Jẹ́nẹ́sísì 11:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wà láàyè fún ọdún mọ́kàndínlọ́gọ́fà (119) lẹ́yìn ìbí Tẹ́rà, ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin mìíràn.

Jẹ́nẹ́sísì 11

Jẹ́nẹ́sísì 11:17-27