Jẹ́nẹ́sísì 11:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wà láàyè fún igba ọdún (200) lẹ́yìn tí ó bí Náhórì, ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin mìíràn.

Jẹ́nẹ́sísì 11

Jẹ́nẹ́sísì 11:15-29