Jẹ́nẹ́sísì 11:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó tún wà láàyè lẹ́yìn tí ó bí Ṣérúgì fún igba-ó-lé-méje ọdún (207), ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin mìíràn.

Jẹ́nẹ́sísì 11

Jẹ́nẹ́sísì 11:18-30