Jẹ́nẹ́sísì 11:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ébérì sì wà láàyè fún irínwó-ó-lé-ọgbọ̀n ọdún (430) lẹ́yìn tí ó bí Pélégì, ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin mìíràn.

Jẹ́nẹ́sísì 11

Jẹ́nẹ́sísì 11:7-20