Jẹ́nẹ́sísì 11:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wà láàyè fún ọdún mẹ́talénírínwó (403) lẹ́yìn tí ó bí Ṣélà, ó sì bí àwọn ọmọbìnrin àti àwọn ọmọkùnrin mìíràn.

Jẹ́nẹ́sísì 11

Jẹ́nẹ́sísì 11:11-18