Jẹ́nẹ́sísì 10:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì jẹ́ ògbójú ọdẹ níwájú Olúwa; nítorí náà ni a ṣe ń wí pé, “Bí Nímúrọ́dù-ògbójú ọdẹ níwájú Olúwa.”

Jẹ́nẹ́sísì 10

Jẹ́nẹ́sísì 10:3-17