Jẹ́nẹ́sísì 10:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

(Láti ọ̀dọ̀ àwọn wọ̀nyí ni àwọn tí ń gbé agbégbé tí omi wà ti tàn ká agbégbé wọn, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà wọn, ìdílé wọn ní orílẹ̀ èdè wọn, olúkúlùkù pẹ̀lú èdè tirẹ̀).

Jẹ́nẹ́sísì 10

Jẹ́nẹ́sísì 10:1-9