Jẹ́nẹ́sísì 10:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Agbègbè ibi tí wọn ń gbé bẹ̀rẹ̀ láti Méṣà títí dé Ṣéfárì, ní àwọn ilẹ̀ tó kún fún òkè ní ìlà oòrùn.

Jẹ́nẹ́sísì 10

Jẹ́nẹ́sísì 10:24-32