Jẹ́nẹ́sísì 10:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ébérì sì bí ọmọ méjì:ọ̀kan sì ń jẹ́ Pélégì, nítorí ní ìgbà ayé rẹ̀ ni ilẹ̀ ayé pín sí oríṣìíríṣìí ẹ̀yà àti èdè. Orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni Jókítanì.

Jẹ́nẹ́sísì 10

Jẹ́nẹ́sísì 10:19-32