Jẹ́nẹ́sísì 10:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni ìran àwọn ọmọ Nóà: Ṣémù, Ámù àti Jáfétì, tí àwọn náà sì bí ọmọ lẹ́yìn ìkún omi.

Jẹ́nẹ́sísì 10

Jẹ́nẹ́sísì 10:1-11