Jẹ́nẹ́sísì 1:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, Ọlọ́run dá ènìyàn ní àwòrán ara rẹ̀,ní àwòrán Ọlọ́run ni ó dá a;akọ àti abo ni ó dá wọn.

Jẹ́nẹ́sísì 1

Jẹ́nẹ́sísì 1:26-31