Jẹ́nẹ́sísì 1:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run sì wí pé, “Jẹ́ kí omi kí ó kún fún àwọn ohun alààyè, kí àwọn ẹyẹ kí ó sì máa fò ní òfuurufú.”

Jẹ́nẹ́sísì 1

Jẹ́nẹ́sísì 1:15-26