Jẹ́nẹ́sísì 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ayé sì wà ní rúdurùdu, ó sì ṣófo, òkùnkùn sì wà lójú ibú omi, Ẹ̀mí Ọlọ́run sì ń rá bàbà lójú omi gbogbo.

Jẹ́nẹ́sísì 1

Jẹ́nẹ́sísì 1:1-7