Jẹ́nẹ́sísì 1:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

láti ṣàkóso ọ̀sán àti òru àti láti pààlà sí àárin ìmọ́lẹ̀ àti òkùnkùn: Ọlọ́run sì rí i pé ó dára.

Jẹ́nẹ́sísì 1

Jẹ́nẹ́sísì 1:15-26