Jẹ́nẹ́sísì 1:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí wọn ó jẹ́ ìmọ́lẹ̀ ní ojú ọ̀run, láti tan ìmọ́lẹ̀ sí orí ilẹ̀.” Ó sì rí bẹ́ẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 1

Jẹ́nẹ́sísì 1:12-25