Jẹ́nẹ́sísì 1:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run sì pe ilẹ̀ gbígbẹ náà ní “Ilẹ̀” àti àpapọ̀ omi ní “Òkun:” Ọlórun sì rí i wí pé ó dára.

Jẹ́nẹ́sísì 1

Jẹ́nẹ́sísì 1:9-20