Jákọ́bù 5:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Góòlù òun sílífà yín díbàjẹ́; ìbàjẹ́ wọn ni yóò sì ṣe ẹlẹ́rìí sí yín, tí yóò sì jẹ ẹran ara yín bí iná. Ẹ̀yin tí kó ìsúra jọ de ọjọ́ ìkẹyìn.

Jákọ́bù 5

Jákọ́bù 5:1-5