Jákọ́bù 5:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì tún gbàdúrà, ọ̀run sì tún rọ̀jò, ilẹ̀ sì so èso rẹ̀ jáde.

Jákọ́bù 5

Jákọ́bù 5:14-20