Jákọ́bù 5:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àdúrà ìgbàgbọ́ yóò sì gba aláìsàń náà là, Olúwa yóò sì gbé e dìde; bí ó bá sì ṣe pé ó ti dẹ́sẹ̀, a ó dárí jì í.

Jákọ́bù 5

Jákọ́bù 5:9-20