Jákọ́bù 5:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Inú ẹnikẹ́ni ha bàjẹ́ nínú yín bí? Jẹ́ kí ó gbàdúrà. Inú ẹnikẹ́ni ha dùn? Jẹ́ kí ó kọrin mímọ́.

Jákọ́bù 5

Jákọ́bù 5:11-18