Jákọ́bù 5:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sáà wò ó, àwa a máa ka àwọn tí ó fara dà ìyà sí ẹni ìbùkún. Ẹ̀yin ti gbọ́ ti sùúrù Jóòbù, ẹ̀yin sì rí ìgbẹ̀yìn tí Olúwa ṣe; pé Olúwa kún fún ìyọ́nú, ó sì ní àánú.

Jákọ́bù 5

Jákọ́bù 5:4-12