Jákọ́bù 4:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Aṣòfin àti onídàájọ́ kan ṣoṣo ní ó ń bẹ, àní ẹni tí ó lè gbà là tí ó sì le parun, Ṣùgbọ́n ta ni ìwọ tí ó ń dá ẹni kejì rẹ lẹ́jọ́?

Jákọ́bù 4

Jákọ́bù 4:5-17