Jákọ́bù 3:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí olúkúlùkù ẹ̀dá ẹranko, àti ti ẹyẹ, àti ti ejò, àti ti ohun tí ó ń bẹ ní òkun, ni à ń tù lójú, tí a sì ti tù lójú láti ọwọ́ ẹ̀dá ènìyàn wá.

Jákọ́bù 3

Jákọ́bù 3:1-13