Jákọ́bù 3:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nitorí nínú ohun púpọ̀ ni gbogbo wa ń ṣe àṣìse. Bí ẹni kan kò bá sì sì ṣe nínú ọ̀rọ̀, òun náà ni ẹni pípé, òun ni ó sì le kó gbogbo ara ní ìjánu.

Jákọ́bù 3

Jákọ́bù 3:1-6