Jákọ́bù 1:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìsìn mímọ́ àti aláìléèérí níwájú Ọlọ́run àti baba ni èyí, láti máa bojú tó àwọn aláìní-baba àti àwọn opó nínú ìpọ́njú wọn, àti láti pa ara rẹ̀ mọ́ láì lábàwọ́n kúrò nínú ayé.

Jákọ́bù 1

Jákọ́bù 1:18-27