Jákọ́bù 1:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó pinnu láti fi ọ̀rọ̀ òtítọ́ bí wa kí àwa kí ó le jẹ́ àkọ́so nínú ohun gbogbo tí ó dá.

Jákọ́bù 1

Jákọ́bù 1:15-24