Ísíkẹ́lì 9:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí mo ṣe ń fetí sí èyí, O tún sọ fún àwọn yòókù pé, “Tẹ̀lé ọkùnrin náà lọ sáàrin ìlú láti pa láì dásí àti láì ṣàánú rárá.

Ísíkẹ́lì 9

Ísíkẹ́lì 9:1-9