Ísíkẹ́lì 8:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó mú mi wá sí ibi àgbàlá ilé Olúwa, lẹ́nu ọ̀nà tẹ́ḿpìlì Olúwa, wọn kọjú sí ìlà òòrùn, wọ́n sì ń foríbalẹ̀ fún òòrùn ní apá ìlà òòrùn.

Ísíkẹ́lì 8

Ísíkẹ́lì 8:12-18