Ísíkẹ́lì 8:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó tún sọ fún mi pé, “Ìwọ yóò rí wọn tí wọ́n ń ṣe àwọn ohun mìíràn tó burú jù bẹ́ẹ̀ lọ.”

Ísíkẹ́lì 8

Ísíkẹ́lì 8:12-15