Ísíkẹ́lì 7:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo ṣetán láti tú ìbìnú gbígbóná mi lé ọ lórí àti láti lo ìbínú mi lórí rẹ gẹ́gẹ́ bí gbogbo ọ̀nà rẹ, n ó sì san án fún ọ gẹ́gẹ́ bi gbogbo ìwà ìríra rẹ.

Ísíkẹ́lì 7

Ísíkẹ́lì 7:1-10