Ísíkẹ́lì 7:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wàhálà lórí wàhálà yóò dé, ìdágìrì sókè lórí ìdágìrì, Nígbà náà ni wọn ó wá ìran lọ́dọ̀ wòlíì; ṣùgbọ́n ẹ̀kọ́ òfin yóò parun lọ́dọ̀ àlùfáà, bẹ́ẹ̀ ni ìmọ̀ràn yóò ṣègbé lọ́dọ̀ àwọn alàgbà.

Ísíkẹ́lì 7

Ísíkẹ́lì 7:19-27